Song parody of

Ọ̀JẸ̀JẸ̀

by Àtàndá

Here's where you get creative! Use our cool song parody creator to make a totally new musical idea and lyrics for the Ọ̀JẸ̀JẸ̀ song by Àtàndá.

Simply click on any word to get rhyming words suggestion to use instead of the original ones. You may also remove or alter entire lines if needed — when you're done save your work and share it with our community — have fun!

  • English (English)
  • Français (French)
  • Español (Spanish)

Eh Eh Ọ̀jè̩jè̩ Ọmọ nlá abara gẹgẹ wọn ni o ma f'ínú w'énú ko ma ba jẹ iwọ Osika i wi fun ni ijọ ohun o sekà Ọ̀jè̩jè̩ Ọ̀jè̩jè̩ Ah Ọ̀jè̩jè̩ Ọ̀jè̩jè̩ ooo Ọ̀jè̩jè̩ Ọ̀jè̩jè̩ ooo bi mba p'ọ̀jẹ̀jè̩ o Ọ̀jè̩jè̩ o awo mi ni Ọ̀jè̩jè̩ Ọ̀jè̩jè̩ ooo Ọ̀jè̩jè̩ Ọ̀jè̩jè̩ ooo Bi mba p'ọ̀jẹ̀jè̩ mi Ọ̀jè̩jè̩ o awo mi ni Ẹni o se iwaju ẹni ko ma tun gbọdọ sẹyin ẹni Aiye kòótó̩ ẹyin o suwọn ibi ori d'ani si la n gbe jaiye Nigba to ń bẹ l'aiye ọrẹ mi wọn o le f'ẹjú fun ọ Àkukọ kọ lẹyin ọmọkunrin wọn wa n sọrọ eniyan Ọ̀jẹ̀jẹ̀ kilode t'aiye yi o gún mọ Lagbaja lohun ọrẹ rẹ kori kosun ọrẹ kori kosun rẹ Igba ti soro de ọrẹ na pápá bora Igba t'ikú de wọn d'asọ ẹbi gbogbo aiye lo gbọ Ẹjẹ ka se igba ile jẹjẹ a o mọ b'igba oko yio so bi o so O dun la n j'ẹ̀fọ̀ ọrẹ wọn ni t'ile oge t'oge jẹ Ọ̀jẹjẹ mọ mọ sọni barin oo Ọ̀jẹjẹ oo sọni gbọkan rẹ le Ẹbami p'ọ̀jẹ̀jẹ̀ Ọ̀jè̩jè̩ Ọ̀jè̩jè̩ ooo Ọ̀jè̩jè̩ o o Ọ̀jè̩jè̩ ooo Bi mba p'ọ̀jẹ̀jè̩ o Ọ̀jè̩jè̩ o awo mi ni Ọ̀jè̩jè̩ Ọ̀jè̩jè̩ ooo Ọ̀jè̩jè̩ o o Ọ̀jè̩jè̩ ooo Bi mba p'ọ̀jẹ̀jè̩ mi Ọ̀jè̩jè̩ o awo mi ni Ọ̀jè̩jè̩ na my guy Ọ̀jè̩jè̩ na better person o Ọ̀jè̩jè̩ na chop make i chop o make life for better But no be when life better you go know your true friends Ọ̀jè̩jè̩ Dem go call you angel o when dem dey chop from you Ọ̀jè̩jè̩ Dem go call you nwanem o when dem dey eat from you Ọ̀jè̩jè̩ But when trouble come na then you go know your true friends Ọ̀jè̩jè̩ Ọ̀jẹjẹ Mọ mọ sọni barin oo Ọ̀jẹjẹ oo Sọni gbokan rẹ le Ẹbami p'ọ̀jẹ̀jẹ̀ Ọ̀jè̩jè̩ Ọ̀jè̩jè̩ o o Ọ̀jè̩jè̩ ooo Ọ̀jè̩jè̩ o o Bi mba p'ọ̀jẹ̀jè̩ mi Ọ̀jè̩jè̩ o awo mi ni Ọ̀jè̩jè̩ Ọ̀jè̩jè̩ ooo Ọ̀jè̩jè̩ o o o o Ọ̀jè̩jè̩ ooo Bi mba p'ọ̀jẹ̀jè̩ mi Ọ̀jè̩jè̩ o awo mi ni Ọ̀jè̩jè̩ Ọ̀jè̩jè̩ o o Eh Ọ̀jè̩jè̩ mi o Ọ̀jè̩jè̩ o o Eh bi mba p'ọ̀jẹ̀jè̩ ẹẹ Ọ̀jè̩jè̩ o awo mi ni Wọn ni o ma fi inu wenu aiye nika Ọ̀jè̩jè̩ o o Ọ̀jè̩jè̩ o o Ọ̀jè̩jè̩ o o Ọ̀jè̩jè̩ wọn ni o ma finu wenu ko ma ba jẹ iwọ Ọ̀jè̩jè̩ Ọ̀jè̩jè̩ o o awo mi ni Ma finu wenu Ọ̀jè̩jè̩ eh eh eh eh eh eh Ọ̀jè̩jè̩ o o Sọni ba rin Ọ̀jè̩jè̩ mi Ọ̀jè̩jè̩ o o Ọ̀jè̩jè̩ ọmọ nla ọmo nla Ọ̀jè̩jè̩ o o awo mi ni Ọmọ nla Ah Ọmo nla ma finu wenu Aiye eh eh Ọ̀jè̩jè̩ oooo Aiye soro oh oh Ma finu wenu ah Ọ̀jè̩jè̩ oooo Ọmọ nla Ọ̀jè̩jè̩ O ba ma finu wenu Ọ̀jè̩jè̩ o o awo mi ni

Done creating your parody?

Don't keep it to yourself! Save it now so you can share it with the rest of the world!

Browse Lyrics.com

Quiz

Are you a music master?

»
What is the key of Bohemian Rhapsody?
A Bb major
B B major
C F major
D Bb minor

Free, no signup required:

Add to Chrome

Get instant explanation for any lyrics that hits you anywhere on the web!

Free, no signup required:

Add to Firefox

Get instant explanation for any acronym or abbreviation that hits you anywhere on the web!

Àtàndá tracks

On Radio Right Now

Loading...

Powered by OnRad.io


Think you know music? Test your MusicIQ here!