JESU NASARETI
ADEYINKA ALASEYORI
Watch: New Singing Lesson Videos Can Make Anyone A Great Singer
Jesu lon da mi lola Lon da mi lola Jesu lon segun funmi Lon segun funmi Gbogbo eniyan se on da e lola On da wa lola Se on segun fun e On segun fun wa Oji oku dide Omu aro lara da O so agan do lomo Jesu ti nasareti o Oti ya Jesu ti nasareti Ti nasareti Oti ranmilowo Ti nasareti Jesu ti nasareti Jesu ti nasareti Oti ranmilowo Jesu ti nasareti Jesu ti nasareti Ti nasareti Ewa wo bo se ranmilowo Ti nasareti Jesu ti nasareti Jesu ti nasareti Oti ranmilowo Jesu ti nasareti Ewa wo bo se se Ewa wo bo se se Awa eniyan ojosi Omu wa losi bi giga Omu ogo jade E yen ninu ofo wa Ebi ore ara Won lero pe a le de bi Bio se wo adani waye To ti wa leyin Aye wa nba wa dupe Won ki wa kuorire Jesu ti nasareti Jesu ti nasareti Oti ranmilowo Jesu ti nasareti Jesu ti nasareti Jesu ti nasareti Oti ranmilowo Jesu ti nasareti Eniyan ti se bi eniyan Olorun duro bi olorun Lori oro mi Onwa jo ota mi loju Eniyan ti sebi eniyan Olorun jewo agbara Lori oro mi Owa ya otami lenu Jesu ti nasareti Jesu ti nasareti Oti ranmilowo Jesu ti nasareti Ewa gbo nipa re Aye e je aso nipa re Awo kilu mo lonje Baba dada Oloyun ara re O bi ra re Otun so ra re loruko Omo alade alafia Ijoba yio wa lejika re Jesu ti nasareti Jesu ti nasareti Oti ranmilowo Jesu ti nasareti Jesu ti nasareti Jesu ti nasareti Oti ranmilowo Jesu ti nasareti Je je je je je je oh Jesus Jesus Oruko re o lagbara Jesu ti nasareti Jesu ti nasareti Oti ranmilowo Jesu ti nasareti Je je je je je je oh Jesus Jesus Oruko yen on gbe ku mio Jesu ti nasareti Jesu ti nasareti Oti ranmilowo Jesu ti nasareti Yinka favourite singer Yin tide o Alaseyori Gbogbo aye loti mo Pe mo ri anu gba gan ni Jesu ti nasareti Jesu ti nasareti Oti ranmilowo Jesu ti nasareti Glorious minister Yin tide o Alaseyori Gbogbo aye de loti mo Mo ri anu gba gidi Jesu ti nasareti Jesu ti nasareti Oti ranmilowo Jesu ti nasareti Celebrated minister Tide o Global minister lon je Gbogbo aye loti mo Pe yinka ri anu gba ni se Jesu ti nasareti Jesu ti nasareti Oti ranmilowo Jesu ti nasareti Ape mo ra lan pe temidire Oje so ti re Emi ra anu gba Se wo no ranu gba o Jesu ti nasareti Jesu ti nasareti Oti ranmilowo Jesu ti nasareti Je je je je je je oh Jesus Jesus Se oruko yen gbe ku mi Jesu ti nasareti Jesu ti nasareti Oti ranmilowo Jesu ti nasareti Je je je je je je oh Jesus Jesus Oruko yen olagbara gan Jesu ti nasareti Jesu ti nasareti Oti ranmilowo Jesu ti nasareti Na you wey matter For my matter Adaniwaye iwo lo matter Ninu matter mi Arugbo ojo O gbe matter mi sori Aye wa npa riwo ohun ni Bio se wo leyin mi Aye oba yo mio Jesu ti nasareti Jesu ti nasareti Oti ranmilowo Jesu ti nasareti Jesu ti nasareti Ti nasareti E wo bo se gbemi dide Ti nasareti o Jesu ti nasareti Jesu ti nasareti Oti ranmilowo Jesu ti nasareti Je je je je je je oh Jesus Jesus Oruko yen olagbara gan Jesu ti nasareti Jesu ti nasareti Oti ranmilowo Jesu ti nasareti Celebrated minister Tide o Yinka alaseyori Gbogbo aye loti mo Pe mo ri anu gba ni Jesu ti nasareti Jesu ti nasareti Oti ranmilowo Jesu ti nasareti
The easy, fast & fun way to learn how to sing: 30DaySinger.com
Citation
Use the citation below to add these lyrics to your bibliography:
Style:MLAChicagoAPA
"JESU NASARETI Lyrics." Lyrics.com. STANDS4 LLC, 2024. Web. 13 May 2024. <https://www.lyrics.com/lyric-lf/11813849/ADEYINKA+ALASEYORI/JESU+NASARETI>.
Discuss the JESU NASARETI Lyrics with the community:
Report Comment
We're doing our best to make sure our content is useful, accurate and safe.
If by any chance you spot an inappropriate comment while navigating through our website please use this form to let us know, and we'll take care of it shortly.
Attachment
You need to be logged in to favorite.
Log In