Asiwaju

Oriyomi Kehinde

0 fans

Oriyomi Kehinde


5:37

 Struggling with Asiwaju? Become a better singer in 30 days with these videos!

Jerryson production
S'asiwaju nie loni? ooma rora
Awon tiwon nto e leyin, iwaju nonle
Igba losun kan e loni, ranti ola oo
Igba loyi kan e loni
Ma gbagbe ola oo
Oni lari o keya wu'wa
Te o fi ni ola rere
Agba joko o feyinti
Won nke loju ke nimu
O f'ana e gbin oun rere
Loje kole yan fanda
Beyan o bimo tobi irorun
A r'awon topo se omo fun
Asiwaju se pele o, un-un hun
Asiwaju se pele
Niyanju ati se-rere
S'asiwaju nie loni? ooma rora
Awon tiwon nto e leyin, iwaju nonle
Igba losun kan e loni, ranti ola oo
Igba loyi kan e loni
Ma gbagbe ola oo
MashaAllah
Igberaga ona kan ni
Toya sona ati parun
Olohun maje kin wuwa, t'awon fans fi nbinu
Kin ma wa ninu awon ijo
Celebrity to ngara
T'awon fans ba npewon, won a kaparu bi tata
T'awon fans mi yato
Won nponmile o, mose tiwon
S'asiwaju nie loni? ooma rora
Awon tiwon nto e leyin, iwaju nonle
Igba losun kan e loni, ranti ola oo
Igba loyi kan e loni
Ma gbagbe ola oo
Mio ni kama po t'ansebe
Ki temi ma sha yi sina
Aniyan mi wa bosewa, mio ri kèéta mu nise
Tènbèlèkun pelu òtè o, mio niwa yen rara
Mo ntepa mose loni pupo
Kinle jere arami
Kinma pasán kinma se sòfò
T'asiko yen ba detan
S'asiwaju nie loni? ooma rora
Awon tiwon nto e leyin, iwaju nonle
Igba losun kan e loni, ranti ola oo
Igba loyi kan e loni
Ma gbagbe ola oo
Ka jiya kato ke joro, Olohun o je kogbe
Oruko tiwa ka gbiyanju
Kawa naa sore kan
Enikan, meji ninu akorin
Ka funwon niwon talese
Publicity lojaju, kon d'enikan mo lati arawa
Ina to gbayi loju aàrò
L'eyi toni ogunna ninu
S'asiwaju nie loni? ooma rora
Awon tiwon nto e leyin, iwaju nonle
Igba losun kan e loni, ranti ola oo
Igba loyi kan e loni
Ma gbagbe ola oo
Upcoming pelu aniyan
Toni lokan ko dewaju
Bawo l'aniyan re sewa?
Seni tonbe niwaju
Sebi ko subu kole koja?
Lowa lokan re koso
Tabi kopon naa sun kan e, lori naiyan dada
Eyi toba ro a je tie, asiwaju oni jabo
S'asiwaju nie loni? ooma rora
Awon tiwon nto e leyin, iwaju nonle
Igba losun kan e loni, ranti ola oo
Igba loyi kan e loni
Ma gbagbe ola oo
Olohun maje njorami loju
Emi oni jorami loju
K'olohun maje njorami loju
Emi oni jorami loju
Teba rimi kema pemi
Emi oni jorami loju
Teba kimi moma dahun o, emi oni jorami loju
Apami o ga j'ejika milo
Emi o ni jorami loju
Tori kinto no fans mo sadua gan, kolohun semi leniyan
T'aye ari tiwon a mape, lotun losi konma korin mi
Olohun maje njorami loju
Emi oni jorami loju
K'olohun maje njorami loju
Emi oni jorami loju
Teba rimi kema pemi
Emi oni jorami loju
Teba kimi moma dahun o, emi oni jorami loju
Apami o ga j'ejika milo
Emi o ni jorami loju
Odun tipe ta tinba bo, oriyomi ojuri
Orin fuji lati 1988, a seyen di 2007
Moyi pada sorin esin
Ni gbigba adua bade
Gbogbo aye loti dawa mo
P'oriyomi ogo ni
Olohun maje njorami loju
Emi oni jorami loju
K'olohun maje njorami loju
Emi oni jorami loju
Teba rimi kema pemi
Emi oni jorami loju
Teba kimi moma dahun o, emi oni jorami loju
Apami o ga j'ejika milo
Emi o ni jorami loju

 Struggling with Asiwaju? Become a better singer in 30 days with these videos!

Written by: Oriyomi Sanni

Lyrics © DistroKid

Lyrics Licensed & Provided by LyricFind

Discuss the Asiwaju Lyrics with the community:

0 Comments

    Citation

    Use the citation below to add these lyrics to your bibliography:

    Style:MLAChicagoAPA

    "Asiwaju Lyrics." Lyrics.com. STANDS4 LLC, 2024. Web. 28 Apr. 2024. <https://www.lyrics.com/lyric-lf/12118033/Oriyomi+Kehinde/Asiwaju>.

    Missing lyrics by Oriyomi Kehinde?

    Know any other songs by Oriyomi Kehinde? Don't keep it to yourself!

    Browse Lyrics.com

    Quiz

    Are you a music master?

    »
    What song did this line "Well shake it up baby now ..." come from?
    A The Chocolates - Careless Wispa
    B The Dung Beetles - Waiter There’s Some Funk in my Soup
    C The Beatles - Twist And Shout
    D Pink Floyd - Another Brick In The Wall

    Free, no signup required:

    Add to Chrome

    Get instant explanation for any lyrics that hits you anywhere on the web!

    Free, no signup required:

    Add to Firefox

    Get instant explanation for any acronym or abbreviation that hits you anywhere on the web!

    Oriyomi Kehinde tracks

    On Radio Right Now

    Loading...

    Powered by OnRad.io


    Think you know music? Test your MusicIQ here!