Ìlú Ìbàdàn 1829

Timmystar

0 fans

Timmystar


4:05

 Watch: New Singing Lesson Videos Can Make Anyone A Great Singer

................
Ní bo nì ǹbá wà
Tí ǹ bá wà ńilé bàbá mi
Scatter.......
Ìbàdàn lọ mọ̀, Ó mọ̀ láyípo
Àwá tí dẹ́ a fẹ́ gbò de
Ìbàdàn lọ mọ̀, Ó mọ̀ láyípo
Àwá tí dẹ́ a fẹ́ gbò de
Ìbàdàn lọ mọ̀, Ó mọ̀ láyípo
Àwá tí dẹ́ a fẹ́ gbò de
Ṣe ìwọ ti dé òkè àrẹ
Níbi tí láyípo wà
Só tí dé oríta mẹ́rin
Níbi tí ọrọ̀ ajé sọlẹ̀ sí
Ògùnpa bẹẹrẹ òjé
Sóti dé màpó hall
Ilé tó dàgbà jù ní ìbàdàn
Ó lọ padà ja Cocoa House
Ilé tó ga jù lábà
Ìlú sábó ńkó
Àbókí séríkí mọ̀nà
Sóti dé ọjà ọba
Ibi tí Adégbọrọ̀ wà
Sáńgo mọ àpẹtẹ
Àlàyé pọ̀ ni ológúnẹrú
Agodi Gra
Àwọn olówó ọlọ́ nà
Challenge mọ́ àkóbọ́
Ajé olókun mímọ́
Ìlú ọlọ́ba lóyè
Fáṣítì àti poly
Gate o kéré rárá
Akínyẹlé agbowó òjọ́ọ̀
Ìbàdàn rẹwà púpọ̀
Ìbàdàn lọ mọ̀, Ó mọ̀ láyípo
Àwá tí dẹ́ a fẹ́ gbò de
Ìbàdàn lọ mọ̀, Ó mọ̀ láyípo
Àwá tí dẹ́ a fẹ́ gbò de
Ìbàdàn lọ mọ̀, Ó mọ̀ láyípo
Àwá tí dẹ́ a fẹ́ gbò de
Aah ní bo nì ǹbá wà
Tí ǹ bá wà ńilé bàbá mi
Tí ń bá dé lágalú
Ọrọ̀ àpátà májà
Ebá mi pé bàbá onílù
Èmi jẹ ọmọ ìwó road
Olódó alápatà
Níbi tí àwon àgbẹ̀ wà
Tó ba wọlé sí gbági
Ẹ bá mi kí Ìyá Alásọ
Ọlọ́rọ̀ pọ̀ ní ẹgbẹ́dá
Since 1829
Isé àgbẹ̀ là wa ń ṣé
Amúlóko ìlú idán
Ìbàdàn airport ńkọ́
E gbéra kó di òyó
Eyàn aláàfin ọ̀yọ́
Jẹ mú ọ lọ sí òkè ògùn
Ibàràpá mo ti ńbọ̀
Dákun bámi bọ sílé
Lóní sele sele oh
Olú ìbàdàn of ìbàdàn land
Ìbàdàn mọ̀ èsì ògọ̀
Afi ìkarahun fọ́kọ mu
Níbo ni ǹbá wà
Ọmọ ìbàdàn kíni so rẹ
Kílo jẹ lá nàá
Kílo fi jó kòó oh
Ọmọ Ìbàdàn kí ni sọ rẹ
Kílo jẹ lá nà
Kílo fi jó kò oh
Scrii Scriipo.........

 The easy, fast & fun way to learn how to sing: 30DaySinger.com

Written by: Tobi Oladokun

Lyrics © DistroKid

Lyrics Licensed & Provided by LyricFind

Discuss the Ìlú Ìbàdàn 1829 Lyrics with the community:

0 Comments

    Citation

    Use the citation below to add these lyrics to your bibliography:

    Style:MLAChicagoAPA

    "Ìlú Ìbàdàn 1829 Lyrics." Lyrics.com. STANDS4 LLC, 2024. Web. 1 May 2024. <https://www.lyrics.com/lyric-lf/12407699/Timmystar/%C3%8Cl%C3%BA+%C3%8Cb%C3%A0d%C3%A0n+1829>.

    Missing lyrics by Timmystar?

    Know any other songs by Timmystar? Don't keep it to yourself!

    Browse Lyrics.com

    Quiz

    Are you a music master?

    »
    "Another one bites _______"?
    A the tounge
    B the bun
    C the air
    D the dust

    Free, no signup required:

    Add to Chrome

    Get instant explanation for any lyrics that hits you anywhere on the web!

    Free, no signup required:

    Add to Firefox

    Get instant explanation for any acronym or abbreviation that hits you anywhere on the web!

    Timmystar tracks

    On Radio Right Now

    Loading...

    Powered by OnRad.io


    Think you know music? Test your MusicIQ here!