Esè Odò

Ayo Nefretiti, Fixi

0 fans

Fixi


4:01
#1

 Become A Better Singer In Only 30 Days, With Easy Video Lessons!

Ìpè tó dun bá wa lójijì
Eni tó bá ló lè ròhin rè
Tony cllen ti sípò padà
Sùgbón títí láé nìrántíì re yóó wà


Smile on you are celebrated
Shine on, shine on you are a star
   
Smile on you are celebrated
Smile on, smile on you've done us proud


O Ò ódigbéré o, ódàrìnnàkò

Ó doju àlá o - erínwó

O dewurée jeléjelé

O dàgùtàn-an jemòjemò

O daláàmu tíí je légbèé ògiri

O dàgbàrá òjò - oò yalémó

Ìpàdé desè odò - ó dòhun oo


Smile on you are celebrated
Shine on, shine on you are a star


Ká tóó rérin - ó digbó
Ká tóó réfòn - ó dòdàn o



Héè Diípò gbáyé o - ó seeni ire
Tony cllen ó dòrun-un 're
O gbá'yé o - o hùwàa're
Tony cllen ó dòrun-un 're
Háà ó dòhun o - ó desè odò
Tony cllen ó dòrun-un 're

Ìpéjopò ìdùnnu lafi rántíì re
Tony cllen ó dòrun-un 're

cya, omo àtomoo'mo wón gbèyìn-ìn re
Tony cllen ó dòrun-un 're
Isé tóo se sílè kòlè bàjé láé
Tony cllen ó dòrun-un 're
Ebí, ará , òré o wón sèdáròò 're
Tony cllen ó dòrun-un 're
Àjoyò dídùn ni lafi sè 'dáròò re
Tony cllen ó dòrun-un 're

 The easy, fast & fun way to learn how to sing: 30DaySinger.com

Written by: Francois xavier BOSSARD, Motunrayo OROBIYI, Nicolas GIRAUD

Lyrics © LA FAMILIA DE FRANCIA

Lyrics Licensed & Provided by LyricFind

Discuss the Esè Odò Lyrics with the community:

0 Comments

    Citation

    Use the citation below to add these lyrics to your bibliography:

    Style:MLAChicagoAPA

    "Esè Odò Lyrics." Lyrics.com. STANDS4 LLC, 2024. Web. 16 May 2024. <https://www.lyrics.com/lyric-lf/12914253/Fixi/Ese%CC%80+Odo%CC%80>.

    Missing lyrics by Fixi?

    Know any other songs by Fixi? Don't keep it to yourself!

    Browse Lyrics.com

    Quiz

    Are you a music master?

    »
    Which band released a song titled, 'Deeper Water'?
    A American Authors
    B Mumford & Sons
    C The Beatles
    D The Band Perry

    Free, no signup required:

    Add to Chrome

    Get instant explanation for any lyrics that hits you anywhere on the web!

    Free, no signup required:

    Add to Firefox

    Get instant explanation for any acronym or abbreviation that hits you anywhere on the web!

    Fixi tracks

    On Radio Right Now

    Loading...

    Powered by OnRad.io


    Think you know music? Test your MusicIQ here!