Oyinkan
Tiwadara
Struggling with Oyinkan? Become a better singer in 30 days with these videos!
Óún níkán ló má n wú mi l'órí Oyínkán ló má n yí mi l'órí ò Óún níkán ló tún fún mi l'órí Óún níkán ló má n wú mi l'órí Nígbà tí mo n gbé ní Onírú Tí mi l'ẹ̀fọ́, tí mi lọ́bẹ̀ Onírú My baby baby dey dey for me Ẹbámi dupẹ́ l'ọ́wọ́ ọmọ yìí Pretty pretty lady Ẹlẹ́yinjú ẹgẹ́ baby Original African lady Ẹyín ẹyín t'emí Ẹbámi kírà fún baby Onítèmi tèmi Adúmáradán my baby Óún níkán ló má n wú mi l'órí Oyínkán ló má n yí mi l'órí ò Óún níkán ló tún fún mi l'órí Oyinkan kan Oyinkan kan naaa Ẹ̀yin mummy Ẹkú orí ire Ẹ̀yin daddy adúpẹ́ Iṣẹ nlá lẹ ṣe l'órí Ọmọ Angẹli lẹ jẹ I promise your baby soft life This love don dey sweeter before money enter Óún níkán ló má n wú mi l'órí ( I can count on my baby) Oyínkán ló má n yí mi l'órí (Na this kain feeling make me happy) Óún níkán ló tún fún mi l'órí ( I can count on my baby) Oyínkán kan Oyínkán kan naaa Óún níkán ló má n wú mi l'órí Oyínkán ló má n yí mi l'órí ò Óún níkán ló tún fún mi l'órí Oyínkán kan Oyínkán kan naaa Unavailable unavailable o You're unavailable Dem no go see you o Unavailable unavailable o I'm unavailable o o o ah Óún níkán ló má n wú mi l'órí Oyínkán ló má n yí mi l'órí ò Óún níkán ló tún fún mi l'órí Oyínkán kan Oyínkán kan naaa
Watch: New Singing Lesson Videos Can Make Anyone A Great Singer
Written by: Tiwalola Oluwadara Babalola
Lyrics © O/B/O DistroKid
Lyrics Licensed & Provided by LyricFind
Citation
Use the citation below to add these lyrics to your bibliography:
Style:MLAChicagoAPA
"Oyinkan Lyrics." Lyrics.com. STANDS4 LLC, 2024. Web. 14 May 2024. <https://www.lyrics.com/lyric-lf/12969042/Tiwadara/Oyinkan>.
Discuss the Oyinkan Lyrics with the community:
Report Comment
We're doing our best to make sure our content is useful, accurate and safe.
If by any chance you spot an inappropriate comment while navigating through our website please use this form to let us know, and we'll take care of it shortly.
Attachment
You need to be logged in to favorite.
Log In