Angeli
DJ Plenty & the Yard People
Struggling with Angeli? Become a better singer in 30 days with these videos!
Mo bere wo Mo dide Molo pomi lodo Nseni mo gbo ohun awon angeli Mo reni kan kan Mo wodi keji Moba r'esu to'n rin kiri gbere gbere Oni awon angeli ti tilekun orun Kin ye gbadura mo Amo mo gbo ohun Gbo ohun Awon angeli ti n k'orin Gbo ohun Awon angeli ti n k'orin Won k'orin won k'orin Won k'orin won k'orin Won k'orin won k'orin Won k'orin k'orin k'orin Korin won! Won k'orin ogo Korin won! Won k'orin ogo Emi mimo ha ni kin bo bata Oni ile mimo ni mowa kin kun fope Kin ye beru mo O l'Oluwa ti dariji ese mi Mo gbo fere, mo gbo ilu Mo b'awon korin toripe Mogbo duru Oya gbogbo omo adamo ekorin Gbo ohun Awon angeli ti n k'orin Gbo ohun Awon angeli ti n k'orin Won k'orin won k'orin Won k'orin won k'orin Won k'orin won k'orin Won k'orin k'orin k'orin Korin won! Won k'orin ogo Korin won! Won k'orin ogo Ide mi ti ja Ide mi ti ja Idemi ti ja halelluya Modele ayo Gbo ohun Awon angeli ti n k'orin Gbo ohun Awon angeli ti n k'orin Won k'orin won k'orin Won k'orin won k'orin Won k'orin won k'orin Won k'orin k'orin k'orin Korin won! Won k'orin ogo Korin won! Won k'orin ogo Ogo ni fun Baba Ati Omo Ati Emi mimo
Become A Better Singer In Only 30 Days, With Easy Video Lessons!
Citation
Use the citation below to add these lyrics to your bibliography:
Style:MLAChicagoAPA
"Angeli Lyrics." Lyrics.com. STANDS4 LLC, 2024. Web. 10 May 2024. <https://www.lyrics.com/lyric-lf/4157996/DJ+Plenty+%26+the+Yard+People/Angeli>.
Discuss the Angeli Lyrics with the community:
Report Comment
We're doing our best to make sure our content is useful, accurate and safe.
If by any chance you spot an inappropriate comment while navigating through our website please use this form to let us know, and we'll take care of it shortly.
Attachment
You need to be logged in to favorite.
Log In