Voices (feat. Dasmart)

Ayanfe viral

0 fans

Ayanfe viral


2:47

 Become A Better Singer In Only 30 Days, With Easy Video Lessons!

A lot of voices in my head
Omọ ní career se jẹ́jẹ́
Cause man fit to craze
With voice all stucked in my head
Cause time no Dey
I don tire to Dey wait
Many don meet you for this relay
Fuel your muscle cause time no dey
Cause time no Dey
But kí lamaṣe o
Na Gods time I dey wait
No be say mi ò m'ọ̀dọ bàbá l'ábúlé
Kó má d'ogun wó̩n gb'òkú ká'ìyá mọ́ lé
Kó má lo̩ d'ogun RIP
(Eh eh)
VIP ti dẹ́ní sùn mortuary
(Ah ah)
No worry ọlọ́run bẹ ńidi àrò he's not sleeping
If I no go reach there
I no go reach where I Dey today
How I survive am reach the stage
Ọmọ k'òyémi na by His grace

Ìràwọ̀ Íráwọ́ irawọ íráwọ́ ìràwọ̀
Tó bo rí gbogbo ìràwọ̀
(Ah)
Jọ̀wọ́ fifúnmi eh ah
Ìràwọ̀ Íráwọ́ irawọ íráwọ́
Iràwọ̀ tó bo rí gbogbo ìràwọ̀ jọ̀wọ́ fifúnmi
(Eh)

Ìràwọ̀ òwúrọ̀ ìràwọ̀ ọ̀sáń
Iràwọ̀ ìbejì y'àtọ̀ s'íra wo̩n o
Ìràwọ̀ tálákà à'tolówó
Iràwọ̀ méjéjì kò jọ ra wọn
Fún mi n'íráwọ̀ jẹ́ kiń r'ógo lò
Kiń má lọ lélẹ̀ ní bi t'ẹ́gbẹ́ ti ń gbéra
Why e con Dey be like say I no Dey try oh
I don Dey loose patience oooo
E con be lik say me I don Dey slack oo
Iná mi t'óuń jó o
Kó má ṣe kú lójijì
(Amín o)
Ki máṣe sáré mótò kọlu kẹ̀kẹ́ o è

Ìràwọ̀ Íráwọ́ irawọ íráwọ́ ìràwọ̀
Tó bo rí gbogbo ìràwọ̀ jọ̀wọ́ fifúnmi
Ìràwọ̀ Íráwọ́ irawọ íráwọ́
Iràwọ̀ tó bo rí gbogbo ìràwọ̀

Fest

 The easy, fast & fun way to learn how to sing: 30DaySinger.com

Written by: Awoyemi Dominic, Bamidele Alkanlawon, Thirayo Thirayo

Lyrics © DistroKid

Lyrics Licensed & Provided by LyricFind

Discuss the Voices (feat. Dasmart) Lyrics with the community:

0 Comments

    Citation

    Use the citation below to add these lyrics to your bibliography:

    Style:MLAChicagoAPA

    "Voices (feat. Dasmart) Lyrics." Lyrics.com. STANDS4 LLC, 2024. Web. 30 Apr. 2024. <https://www.lyrics.com/lyric-lf/8017070/Ayanfe+viral/Voices+%28feat.+Dasmart%29>.

    Missing lyrics by Ayanfe viral?

    Know any other songs by Ayanfe viral? Don't keep it to yourself!

    Browse Lyrics.com

    Quiz

    Are you a music master?

    »
    "'Cause I still believe in your faithfulness, 'Cause I still believe in your ______"
    A spoof
    B proof
    C youth
    D truth

    Free, no signup required:

    Add to Chrome

    Get instant explanation for any lyrics that hits you anywhere on the web!

    Free, no signup required:

    Add to Firefox

    Get instant explanation for any acronym or abbreviation that hits you anywhere on the web!

    Ayanfe viral tracks

    On Radio Right Now

    Loading...

    Powered by OnRad.io


    Think you know music? Test your MusicIQ here!