Agbamu

Nopain Igidado

0 fans

Nopain Igidado


3:46

 Watch: New Singing Lesson Videos Can Make Anyone A Great Singer

Ma wa f'owo la mofe mi la oniyan to ba ti Loire
Keyo o Kimi RI
Ma wa f'owo la mofe mi la oniyan to ba ti Loire
Keyo o Kimi RI

Emi omo Mukan Lakan
Emi omo jekan Jekan
Omo t'iya bi to Fi oja aran pan
Lai s'okun eran
Moyato s'awon omo po bi osan to jabo

Emi omo Mukan Lakan
Emi omo jekan Jekan
Omo t'iya bi to Fi oja aran pan Lai s'okun eran
Moyato s'awon omo po bi osan to jabo
Ma wa f'owo la mofe mi la

Emi omo Mukan Lakan
Ma wa f'owo la mofe mi la
Emi omo jekan Jekan
Ogbon ni mofimi Tayo Lo
Omo t'iya bi to Fi oja aran pan
Lai s'okun eran
Ogbon ni mofimi Tayo Lo
Moyato s'awon omo pO
Bi osan to jabo

Sho n be ni? Sho n mo mo ni?
Shey afishey ni? Abi Ogun ni?
Sho Ori ran ni sholoju ni?
Sho on'imu ni sho ngbo run ni?
Sho oleti ni sho n gb'Oro ni ?
Sho olenu ni sho le soro ni?
Soro soke were
Morin pelu agbamu
Moderi nkan gbamu
Motir'Ire gbamu
Motir'Ayo gbamu
Mof'omo Tonidi to fine totun Lomu
Jesus K'Ore dasile
Mok'owo mok'Omo bante pelu Igbadi
Anawo aluwo
Agbawo agbawowo
Ogbeni iya babayin Eni duro
Hmmm Eni duro
Odo ate Lako'Iru Odo ate Lako'Iyo
Oh Y'all
Eyan gidi ni kobami yo
Bi owara ba pe'igba nigbo
Eyokan Lon ha Haha
Shogun laye ni ota eti ha
Ewe oriji L'oni kefori temi Jimi
Kede tun f'owo Jimi
Kede tun f'ola jinmi
Omo onidi nLa khefi gbogbo e Jinmi
Nopain lon soro awon eyan Jimi
Besi mi and see the outcome
Besi mi and see the outcome
Mapada sile Tori tie
Go back to the hood that I Came from
Mafi ye e Pomo Ogun to Yi Nimi pe mide ki SoMo Belgium
Efara bale kos'ofo
Ekawo sori erogo
Ada keso agbeje mowo
K'ara Malo paya yin TogoTogo
Efo de yato s'ewedu o
Emu gidi yato s'obu
Iwo nikan ko lodoti ju o
Situation Loso wa the Dj jentle
MiO gboran MiO gbadun o
Mio ni respect motun buru o
Ibile ni mi ogbodo obey
Take it or leave it or fade away
Mo to so fun e ko dayan mo
Otun mo mi  otun s'eyan mo
Orimi Losan o n shiranran
Tobarimi Loru waya were hnnnh
Oloun Oba Lonimi
Okanran gan denimi
Ijimere tunni mi
Obatala tunni mi
Arikutaku ni mi
Omo iya Shango ni mi
Eleguwa tun ni mi
Iya mi obimo Lemi Owe tun ni
P'eni bama b'esu jeun
Shibi e gan magun Debi
Emi Lomo Mukan Mukan
Jekan Jekan Lakan Lakañ
Eba kikan Obe kikan be aoku
Openi f'Oloun Oba Kan
(Alhamdulilah)
Odo ate Lako'Iru Odo ate Lako'Iyo
Oh Y'all
Eyan gidi ni kobami yo
Bi owara ba pe'igba nigbo Eyokan Lon ha
Haha
Shogun laye ni ota eti ha
Ewe oriji L'oni kefori temi Jimi
Kede tu tun f'owo Jimi
Kede tun f'ola jinmi
Omo onidi nLa khefi gbogbo e Jinmi
Nopain lon soro awon eyan Jimi
Emi ni emi ma ma re o
Omo t'iya bi to Fi oja aran pan
Lai s'okun eran
Moyato s'awon omo pO
Bi osan to jabo

Emi omo Mukan Lakan
Emi omo jekan Jekan
Omo t'iya bi to F'oja aran pan
Lai s'okun eran
Moyato s'awon omo po bi osan to jabo
Emi omo Mukan Lakan
Emi omo jekan Jekan
Omo t'iya bi to F'oja aran pan
Lai s'okun eran
Moyato s'awon omo pO bi osan to jabo

 Become A Better Singer In Only 30 Days, With Easy Video Lessons!

Written by: Temitope Ibrahim

Lyrics © DistroKid

Lyrics Licensed & Provided by LyricFind

Discuss the Agbamu Lyrics with the community:

0 Comments

    Citation

    Use the citation below to add these lyrics to your bibliography:

    Style:MLAChicagoAPA

    "Agbamu Lyrics." Lyrics.com. STANDS4 LLC, 2024. Web. 10 May 2024. <https://www.lyrics.com/lyric-lf/8103535/Nopain+Igidado/Agbamu>.

    Missing lyrics by Nopain Igidado?

    Know any other songs by Nopain Igidado? Don't keep it to yourself!

    Browse Lyrics.com

    Quiz

    Are you a music master?

    »
    The Radiohead song "There there. (The Boney King of Nowhere.)" is from which of their albums?
    A Kid A
    B Hail to the Thief
    C In Rainbows
    D A Moon Shaped Pool

    Free, no signup required:

    Add to Chrome

    Get instant explanation for any lyrics that hits you anywhere on the web!

    Free, no signup required:

    Add to Firefox

    Get instant explanation for any acronym or abbreviation that hits you anywhere on the web!

    Nopain Igidado tracks

    On Radio Right Now

    Loading...

    Powered by OnRad.io


    Think you know music? Test your MusicIQ here!