Iyanu

Oriyomi Kehinde

0 fans

Oriyomi Kehinde


33:18

 Become A Better Singer In Only 30 Days, With Easy Video Lessons!

Mori iyanu ni makkah ati madina, iroyin olohun koja ntaleso tan
Mofe k'olohun je kinle malo, l'ododun fun hajji ati umura
Mori iyanu ni makkah ati madina, iroyin olohun koja ntaleso tan
Mofe k'olohun je kinle malo, l'ododun fun hajji ati umura
MashaaAllah!
Seri iyanu t'olohun se o kere ooo
Iyanu t'olohun se o kere
O jomiloju ninu irin ajo mi, ase esuntere ma wa npada d'ibu
Ase oda pe k'ori ola jiya ri o
Ori to lu igi ori to lu opè naa
T'ori naa o bafo iya ori oun oni gbe
Alhaji ejire t'awon aye ti pemi ri o, l'ero wipe won fin nbomi lashiri
Bon npe alhaji timo bafi erin dahun
Ma f'okan sope k'olohun o tetese ooo
Mo sope k'olohun otete se ooo
Mo nsope k'olohun o tetese
2019 l'olohun base iyanu
Mo pada lo saudi eemeji lodun, iyanu ni
Mori iyanu ni makkah ati madina, iroyin olohun koja ntaleso tan
Mofe k'olohun je kinle malo, l'ododun fun hajji ati umura
Béè
Opo eyan tinrelu makkah tipe
Won ma nroyin b'ise hajji seri o, oorun obe ole dabi anfi okele gbemi
Iroyin o dabi afojuba ayafi
T'eda bale m'oju e debe lo pe
Mo raworase s'olohun o gb'ebe mi
Umura ma l'olohun fi s'akoko o, l'odun kan naa
Loba ti fikun ore odomi, iyanu ni mo pada tun sise hajji mi pe
Iwo ma lose l'oore afikun
Aniyan mi timo da latile o ju tesin lo
Dakun ma ma sope o gba todomi, banse pe
Moti iyanu ni makkah ati madina, iroyin olohun koja ntaleso tan
Mofe k'olohun je kinle malo, l'ododun fun hajji ati umura
Muhammadu f'oju ara e winaaa
Muhammadu f'oju ara e w'ina
Tori k'esin Olohun ma le pare
Otun jiya tori emi ati iwo ni, ase ojiya tori ko bale dan o
Kole d'osho tori emi atie ni
Lada t'awon saabe nfi emi ro, t'ota nseku pawon o lona oro oo
Won f'ana jiya tori oni awa ni
Oun lo d'oni ti awa nfi irorun ri o
More madina mori saare annabi
Mo salamo s'asiwaju esin mi
Eyombo annabi tinutinu e sope
Sola llahu alayhi wa-sallam
Oo! Muhammadu ola omo amina, baba fatimo, koba bami s'ike ati ige fun olawale
Moti iyanu ni makkah ati madina, iroyin olohun koja ntaleso tan
Mofe k'olohun je kinle malo, l'ododun fun hajji ati umura
Olohun mo berue o to loba o to s'agbekele
Iwo salemi oma sin titi lailai
Iwo salemi o masin tinma ma wari fun
Mo gba fun e o to loba o to s'agbekele
Iwo salemi oma sin titi lailai
Iwo salemi o masin tinma ma wari fun
Jalla jalaaluhu oba tao fojuri
To npase tao gbodo lao tele
Oba asooo
Oba aso to f'annabi s'asiwaju
More makkah moriyanu tio lafiwe
Ise olohun tao le fiwe t'eyan kan
Irokirika kahabah kin s'akawe e
O dabi registration pe mowa pe leain mani
Ati submission k'oba gbami ni musulumi
Mo f'ojumi kan kahaba toje ile nla
Mori p'olohuuuuuun
Mori p'olohun oba mi o ni afiwe
Mogba fuuuun, mashaAllah
Mo gba fun olohun ko seku s'aye kan o
Ha, oun salemi o masin titi lailai
Mo egba fun e o to loba o to s'agbekele
Iwo salemi oma sin titi lailai
Iwo salemi o masin tinma ma wari fun
Mo sa safah, marwah mose umura
Meje ni lilo meje pada ni abo ni
Mowa seranti awon obirin ton loyun sinu
Mo sadua fun gbogbo bimobimo aye
Asokale anfani ni k'olohun se
Oungbe ayo koma gbeyin lalai s'omi
Eyi teo mu k'oba se l'omi idera
Bi ti zam-zam, omi zem-zem
Tose fun hajara lojosi, nigba tofi bi ismaila o se idera
Atomi ara ati eje komase d'inira
Mo gba fun olohun tio lafiwe o
Iwo salemi o ma sin titi lailai
Iwo salemi o masin, tinma ma wari fun
Mo egba fun e o to loba o to s'agbekele
Iwo salemi oma sin titi lailai
Iwo salemi o masin tinma ma wari fun
Mo gba fun e o to loba o to s'agbekele
Iwo salemi oma sin titi lailai
Iwo salemi o masin tinma ma wari fun
Seri l'ojo kejo zul hijjah naa lojo
Ti a bere fun ise hajji kodi asepe
A roso mimo (Ihram) fun irin ajo wa
A gba munah lo, a gba munah lo nibi ti gbogbo ibusun
Tonpe ni bed oniha kan fun eniyan kan
Taba jarunpa ao f'ara kan eniyan ni, boje olola ko sope koyato sira
Adua kan ba wasi okan aya mi
Toko tiyawo tiwon nsun sinu yara kanso tosije wipe kogbawon ooo
Bon nsun lale orun bi t'elewon mani
Pese funwon ko kole alara funwon oo
Ti yio maje kiwon ma yin e titi lailai
Iwo shani won o ma yin ton o ma dupe fun
Mo gba fun e o to loba o to s'agbekele
Iwo salemi oma sin titi lailai
Iwo salemi o masin tinma ma wari fun
A lo s'arafa lojo keji ni aye kan, ni arafa nibi tise hajji ti jepe
Eni toba ti gbiyanju duro ni aye naa
Lose hajji, eyan ti kodebe koni di alhaji, o pan dandan kade aye yen
Awa l'arafa mo ranti ojo agbende, ni ojo ti olohun a bere ise
Ti a gbaye se ni owo onikaluku
Se igbiyanju atesin mi sowa le lami
Yah robbi
Oba mi toje oludajo
Mase alaigba igbiyanju pelu esin mi
Wola okan kan at'aniyan timowa fise
Masomi sina tesin mi pelu igbagbo oo
Fimi s'alijanna re kinle rope da
Kiyen o ma j'esi ayo pe mo r'aye wa
Mo gba fun e o to loba o to s'agbekele
Iwo salemi oma sin titi lailai
Iwo salemi o masin tinma ma wari fun
Nigba ta kuro, muzdalifa lakori si, ni aye kan tao sun sile gberefu
Elomiran leri aye sabe bridge
Tasi gbodo sun ni aye ibi ti anwi, otutu, nibe lao wa di mojumo
Mofi aye yen mofi toro fun awon eyan kan, toje ibikibi tile basu toba kawon mo
Ibe nan o sun b'ojo banro nibe mani
Se ibugbe, yowon kuro ninu iśe
Ma tawon loshi je kon pada gbadun aye oo
Toriwo shani won o masin ton o ma dupe fun
Iwo shani won o masin, ton o ma gbola fun
Mo egba fun e o to loba o to s'agbekele
Iwo salemi oma sin titi lailai
Iwo salemi o masin tinma ma wari fun
Mio gbagbe aye kan, jamrah loruko aye naa
Nibi tao lo lati lo soko fun shaiton
Oko meje laso sojukan lojo akoko
Lojo keji, mejemeje lona meta
Ni ojo keta oko meje tun ni lona meta
Base nsoko ni moranti awon eniyan
Boku dede o kon rore gba ni ona kan
Awon alatako, wonse idina funwon
Gbogbo awon toribe fun Allahu mi
Bawa soko fun
Bawa soko fun, awon alatako to ndina mo won o
Ha, konle ma rerin ayo konma ropeda
Mo egba fun e o to loba o to s'agbekele
Iwo salemi oma sin titi lailai
Iwo salemi o masin tinma ma wari fun
Oore ofe nimogba ogbon mi ko, igbiyanju mi nikan ko
Olohun ni, seberawon tose jumi tio funwon
Ol'asiko ti olohun nseke koowa
Oore ofe nimogba ogbon mi ko, igbiyanju mi nikan ko
Olohun ni, seberawon tose jumi tio funwon
Ol'asiko ti olohun nseke koowa
Alore ofe nimogba ogbon mi ko oo
Oore ofe nimogba ogbon mi ko
Igbiyanju mi nikan ko, olohun ni, seberawon tose jumi tio funwon
Ol'asiko ti olohun nseke koowa
Oore ofe nimogba ogbon mi ko, igbiyanju mi nikan ko
Olohun ni, seberawon tose jumi tio funwon
Ol'asiko ti olohun nseke koowa
Oriyomi edakun ejo ema shimi gbo o
Kiise po poju mio so wipe kotope
Sungbon koi toba le se lalekun
Kodin ola olohun ku tori kiitan
Oore to bunmi olohun mi, ma kuro yah robbi kotun ma lekun
Oore ofe nimogba ogbon mi ko, igbiyanju mi nikan ko
Olohun ni, seberawon tose jumi tio funwon
Ol'asiko ti olohun nseke koowa
Seri b'olohun oba seto koye enikankan oo
Ani b'olohun oba seto koye enikankan
A bu ikan kun ase ikan kun yio po juralo
Awon kan t'olohun o ni tete fun o
Awon kan tun wa ton ma lo tio nipe to
Shomi allahu mase je ki temi o tan o, wola iya timo jeri ninu aye
Wola iya timo jeri, ninu ise
Saanu mi mase je kitemi o gbe
Oore ofe nimogba ogbon mi ko, igbiyanju mi nikan ko
Olohun ni, seberawon tose jumi tio funwon
Ol'asiko ti olohun nseke koowa
Eniyan t'olohun ba yan toje alaanu eni, tojepe kotun wa wuwa bi p'osu rara
Afi ki aki onitoun p'oku omoniyan
Oba bamiso rashidi akanmu agunwa
Mentioning the supports & supports of alhaji abdul rasheed agunwa bakare
(C.e.o glory land estate)
Eyi onije asegbeyin aje opo oore
Eniyan t'olohun ba yan toje alaanu eni, tojepe kotun wa wuwa bi p'osu rara
Afi ki aki onitoun p'oku omoniyan
Oba bamiso rashidi akanmu agunwa
Appreciating the supports & supports of alhaji abdul rasheed agunwa bakare
(C.e.o glory land estate)
Oko alhaja balikisu mi mi alarafa nko? Oko oluwatoyin rashidi agunwa
Eniyan t'olohun ba yan toje alaanu eni, tojepe kotun wa wuwa bi p'osu rara
Afi ki aki onitoun p'oku omoniyan
Oba bamiso rashidi akanmu agunwa
Appreciating the supports & supports of alhaji abdul rasheed agunwa bakare
(C.e.o glory land estate)
Oba bami salekun ike fun agunwa
Eniyan t'olohun ba yan toje alaanu eni, tojepe kotun wa wuwa bi p'osu rara
Afi ki a

 Struggling with Iyanu? Become a better singer in 30 days with these videos!

Written by: Oriyomi Sanni

Lyrics © DistroKid

Lyrics Licensed & Provided by LyricFind

Discuss the Iyanu Lyrics with the community:

0 Comments

    Citation

    Use the citation below to add these lyrics to your bibliography:

    Style:MLAChicagoAPA

    "Iyanu Lyrics." Lyrics.com. STANDS4 LLC, 2024. Web. 27 Apr. 2024. <https://www.lyrics.com/lyric-lf/8784551/Oriyomi+Kehinde/Iyanu>.

    Missing lyrics by Oriyomi Kehinde?

    Know any other songs by Oriyomi Kehinde? Don't keep it to yourself!

    Browse Lyrics.com

    Quiz

    Are you a music master?

    »
    The song "Delilah" by Queen was about Freddie Mercury's...
    A Role Model
    B Cat
    C Girlfriend
    D Mother

    Free, no signup required:

    Add to Chrome

    Get instant explanation for any lyrics that hits you anywhere on the web!

    Free, no signup required:

    Add to Firefox

    Get instant explanation for any acronym or abbreviation that hits you anywhere on the web!

    Oriyomi Kehinde tracks

    On Radio Right Now

    Loading...

    Powered by OnRad.io


    Think you know music? Test your MusicIQ here!