Song parody of

Asoju

by ToLmusic

Here's where you get creative! Use our cool song parody creator to make a totally new musical idea and lyrics for the Asoju song by ToLmusic.

Simply click on any word to get rhyming words suggestion to use instead of the original ones. You may also remove or alter entire lines if needed — when you're done save your work and share it with our community — have fun!

  • English (English)
  • Français (French)
  • Español (Spanish)

Ó tú wa sílẹ̀ kúrò nínú gbogbo ìdè ẹ̀sẹ̀ Kalè jẹ́ asojú Kalè jẹ́ asojú rẹ̀ Kalè fi igbesi aiye wa fa ẹlẹsẹ wọ ìjọba ọ̀run Kalè je asoju Asoju ni wa Arabaribiti, Ọlọ́run Oba tó dá gbogbo aiye. O fẹ́ràn ọmọ aráyé ló bá f'ọmọ rè kan ṣoṣo fún wa Láti gbà wa kúrò nínú gbogbo ìdè ẹ̀sẹ̀ Égun òfin ti a gbà l'ọgba Édéni Lọ́jọ́sí Lọ́jọ́sí o Lọ́jọ́sí Lọ́jọ́sí o Lọ́jọ́sí o Lọ́jọ́sí Lọ́jọ́sí o, Lọ́jọ́sí Lọ́jọ́sí o Gbogbo wa lati sẹ̀ lati kùnà ògo Olúwa nitori ọjọ́sí Lọ́jọ́sí o Lọ́jọ́sí Lọ́jọ́sí o Nítorí ọjọ́sí O jiya o Nítorí ọjọ́sí a fi rúbọ Lọ́jọ́sí Lọ́jọ́sí o Lọ́jọ́sí Lọ́jọ́sí o Lọ́jọ́sí, Lọ́jọ́sí, Lọ́jọ́sí, Lọ́jọ́sí Gbogbo wa lati sẹ̀ lati kùnà ògo Olúwa nitori ọjọ́sí Lọ́jọ́sí o Lọ́jọ́sí Lọ́jọ́sí o Nítorí ọjọ́sí O jiya o Nítorí ọjọ́sí a fi rúbọ Lọ́jọ́sí Lọ́jọ́sí o Lọ́jọ́sí Lọ́jọ́sí o O gbà wa sílẹ̀ kúrò nínú gbogbo ìgbèkùn èsè Kalè jẹ́ asojú Kalè jẹ́ asojú rẹ̀ Kalè fi igbesi aiye wa fa ẹlẹsẹ wọ ìjọba ọ̀run Kalè je asoju Asoju ni wa Ó tú wa sílẹ̀ kúrò nínú gbogbo ìdè ẹ̀sẹ̀ Kalè jẹ́ asojú Kalè jẹ́ asojú rẹ̀ Kalè fi igbesi aiye wa fa ẹlẹsẹ wọ ìjọba ọ̀run Kalè je asoju Asoju ni wa For we must all appear before the judgment seat of Christ So that each one may receive what is due for what he has done in the body Whether good or evil. Ìmọ́lẹ̀ aiye lo yẹ ki a jé ̣ Kí a lè fi ọ̀nà han awọn elésè Ti Ọlọ́jọ́ bá dé Ka ma jèbi isẹ́ tó rán wa Ka ma jèbi isẹ́ tó rán wa Ọ̀dájú ọ̀dájú o, Ọ̀dájú ọ̀dájú o Ọ̀dájú ọ̀dájú o, Ọ̀dájú ọ̀dájú o A o jíyìn a o jere iṣẹ́ ọwọ́ wa To bá de to bá de o, to bá dé o o Tó bá dé to bá de o, Tó bá dé to bá de o To bá dé, To bá dé, To bá dé, To bá dé A o jíyìn a o jere iṣẹ́ ọwọ́ wa Tó bá dé tó bá de o, to bá dé o o Tó bá de tó bá de o, Tó bá de tó bá de o Se rere se rere o, se rere onigbagbo se rere o, se rere o Se rere se rere o, Se rere se rere o Oun bo

Done creating your parody?

Don't keep it to yourself! Save it now so you can share it with the rest of the world!

Browse Lyrics.com

Quiz

Are you a music master?

»
Sjoukje Lucie van 't Spijker was the real name of?
A Maggie Rogers
B Maggie MacNeal
C Maggie Reilly
D Maggie Bell

Free, no signup required:

Add to Chrome

Get instant explanation for any lyrics that hits you anywhere on the web!

Free, no signup required:

Add to Firefox

Get instant explanation for any acronym or abbreviation that hits you anywhere on the web!

ToLmusic tracks

On Radio Right Now

Loading...

Powered by OnRad.io


Think you know music? Test your MusicIQ here!