Asoju

ToLmusic

0 fans

ToLmusic


5:33
#1

 The easy, fast & fun way to learn how to sing: 30DaySinger.com

Ó tú wa sílẹ̀ kúrò nínú gbogbo ìdè ẹ̀sẹ̀
Kalè jẹ́ asojú
Kalè  jẹ́ asojú rẹ̀
Kalè fi igbesi aiye wa fa ẹlẹsẹ wọ ìjọba ọ̀run
Kalè je asoju
Asoju ni wa
Arabaribiti, Ọlọ́run  Oba tó dá gbogbo aiye.
O fẹ́ràn ọmọ aráyé
ló bá f'ọmọ rè kan ṣoṣo fún wa
Láti gbà wa kúrò nínú gbogbo ìdè ẹ̀sẹ̀
Égun òfin ti a gbà  l'ọgba Édéni
Lọ́jọ́sí Lọ́jọ́sí o
Lọ́jọ́sí Lọ́jọ́sí o
Lọ́jọ́sí o

Lọ́jọ́sí Lọ́jọ́sí o, Lọ́jọ́sí Lọ́jọ́sí o

Gbogbo wa lati sẹ̀ lati kùnà ògo  Olúwa nitori ọjọ́sí Lọ́jọ́sí o
Lọ́jọ́sí Lọ́jọ́sí o

Nítorí ọjọ́sí O jiya o
Nítorí ọjọ́sí a fi rúbọ
Lọ́jọ́sí Lọ́jọ́sí o
Lọ́jọ́sí Lọ́jọ́sí o
Lọ́jọ́sí, Lọ́jọ́sí, Lọ́jọ́sí, Lọ́jọ́sí

Gbogbo wa lati sẹ̀ lati kùnà ògo  Olúwa nitori ọjọ́sí Lọ́jọ́sí o
Lọ́jọ́sí Lọ́jọ́sí o

Nítorí ọjọ́sí O jiya o
Nítorí ọjọ́sí a fi rúbọ
Lọ́jọ́sí Lọ́jọ́sí o
Lọ́jọ́sí Lọ́jọ́sí o

O gbà wa sílẹ̀  kúrò nínú gbogbo ìgbèkùn èsè
Kalè jẹ́ asojú
Kalè  jẹ́ asojú rẹ̀
Kalè fi igbesi aiye wa fa ẹlẹsẹ wọ ìjọba ọ̀run
Kalè je asoju
Asoju ni wa

Ó tú wa sílẹ̀ kúrò nínú gbogbo ìdè ẹ̀sẹ̀
Kalè jẹ́ asojú
Kalè  jẹ́ asojú rẹ̀
Kalè fi igbesi aiye wa fa ẹlẹsẹ wọ ìjọba ọ̀run
Kalè je asoju
Asoju ni wa

For we must all appear before the judgment seat of Christ
So that each one may receive what is due for what he has done in the body
Whether good or evil.

Ìmọ́lẹ̀ aiye lo yẹ ki a jé ̣
Kí a lè fi ọ̀nà han awọn elésè
Ti Ọlọ́jọ́ bá  dé
Ka ma jèbi isẹ́ tó rán wa
Ka ma jèbi isẹ́ tó rán wa
Ọ̀dájú ọ̀dájú o, Ọ̀dájú ọ̀dájú o
Ọ̀dájú ọ̀dájú o, Ọ̀dájú ọ̀dájú o

A o jíyìn a o jere iṣẹ́ ọwọ́ wa
To bá  de  to bá  de o, to bá dé o o
Tó bá  dé  to bá  de o,  Tó bá  dé  to bá  de o
To bá dé, To bá dé, To bá dé, To bá dé
A o jíyìn a o jere iṣẹ́ ọwọ́ wa
Tó bá  dé  tó bá  de o, to bá dé o o
Tó bá  de  tó bá  de o, Tó bá  de  tó bá  de o
Se rere se rere o, se rere onigbagbo se rere o, se  rere o
Se rere se rere o, Se rere se rere o
Oun bo

 Struggling with Asoju? Become a better singer in 30 days with these videos!

Written by: Tomayo Berida

Lyrics © O/B/O DistroKid

Lyrics Licensed & Provided by LyricFind

Discuss the Asoju Lyrics with the community:

0 Comments

    Citation

    Use the citation below to add these lyrics to your bibliography:

    Style:MLAChicagoAPA

    "Asoju Lyrics." Lyrics.com. STANDS4 LLC, 2024. Web. 3 May 2024. <https://www.lyrics.com/lyric-lf/13785373/ToLmusic/Asoju>.

    Missing lyrics by ToLmusic?

    Know any other songs by ToLmusic? Don't keep it to yourself!

    Browse Lyrics.com

    Quiz

    Are you a music master?

    »
    "And she will always carry on, Something is lost, But something is ________"
    A right
    B gone
    C wrong
    D found

    Free, no signup required:

    Add to Chrome

    Get instant explanation for any lyrics that hits you anywhere on the web!

    Free, no signup required:

    Add to Firefox

    Get instant explanation for any acronym or abbreviation that hits you anywhere on the web!

    ToLmusic tracks

    On Radio Right Now

    Loading...

    Powered by OnRad.io


    Think you know music? Test your MusicIQ here!