Mo l'Olorun

Ola Daniel

1 fan

Ola Daniel

Olanrewaju Daniel Abayomi was born on November 18, 1985 in Owo, Ondo state, he graduated as a sociologist from Tai Solarin University of Education. He started his gospel music career from his teen age.


Year:
2020
#1

 Become A Better Singer In Only 30 Days, With Easy Video Lessons!

Mo l'Olorun to ju gbogbo orisa
Jagunmolu Olori ogun orun ni
Ogun aye ti k'abuku lori mi o
Olori gbogbo ogun l'Olorun mi

Mo l'Olorun to ju gbogbo orisa
Jagunmolu Olori ogun orun ni
Ogun aye ti k'abuku lori mi o
Olori gbogbo ogun l'Olorun mi

Mo l'Olorun to ju gbogbo orisa
Jagunmolu Olori ogun orun ni
Ogun aye ti k'abuku lori mi o
Olori gbogbo ogun l'Olorun mi

Tani iwo oke niwaju serubabeli
A ti bi o wo ko s'agbara fun o mo o
Ogun aye t'o n dun mohuru ti panumo
Jesu Alagbara l'Olori ogun mi

(Eh)Tani iwo oke niwaju serubabeli
Ani a ti bi o wo agbara re ti di ofo
Ogun aye t'o n dun mohuru ti panumo
Jesu Alagbara l'Olori ogun mi

Mo l'Olorun to ju gbogbo orisa
Jagunmolu Olori ogun orun ni
Ogun aye ti k'abuku lori mi o
Olori gbogbo ogun l'Olorun mi

Tal'alagbara ti Jesu ko mo o
Omiran yen da to fe pa mi togotogo
Mo ti ni Jesu Omiran to ju omiran gbogbo
Ajamafitibonse l'Olorun temi
Tani alagbara yen ti Jesu mi ko mo rara
Omiran yen da to fe pa mi togotogo
Mo ti ni Jesu Omiran to ju omiran gbogbo
Ajamafitibonse l'Olorun temi

Mo l'Olorun to ju gbogbo orisa
Jagunmolu Olori ogun orun ni
Ogun aye ti k'abuku lori mi o
Olori gbogbo ogun l'Olorun mi


O wo, o wo ogun esu o wo lulẹ
O wo, o wo ogun esu wo lulẹ
O wo, o  ti wo ogun esu wo patapata
O wo, o wo ogun esu wo lulẹ
(eh)Ogun esu wo lulẹ
Ogun esu wo lulẹ
(eh) ogun aisan ti wo o patapata
Ogun esu wo lulẹ
Ogun gbese ti patapata, o ti wo womuwomu
Ogun esu wo lulẹ
(eh)Ogun ijakule ti wo o patapata
Ogun esu wo lulẹ
Ogun aje ogun oso ti wo o
Ogun esu wo lulẹ

 The easy, fast & fun way to learn how to sing: 30DaySinger.com

 

Written by: Aboladan

Submitted by yommydaniel on July 06, 2021

Discuss these Mo l'Olorun Lyrics with the community:

0 Comments

    Translation

    Translate these lyrics to another language:

    Select another language:

    • - Select -
    • 简体中文 (Chinese - Simplified)
    • 繁體中文 (Chinese - Traditional)
    • Español (Spanish)
    • Esperanto (Esperanto)
    • 日本語 (Japanese)
    • Português (Portuguese)
    • Deutsch (German)
    • العربية (Arabic)
    • Français (French)
    • Русский (Russian)
    • ಕನ್ನಡ (Kannada)
    • 한국어 (Korean)
    • עברית (Hebrew)
    • Gaeilge (Irish)
    • Українська (Ukrainian)
    • اردو (Urdu)
    • Magyar (Hungarian)
    • मानक हिन्दी (Hindi)
    • Indonesia (Indonesian)
    • Italiano (Italian)
    • தமிழ் (Tamil)
    • Türkçe (Turkish)
    • తెలుగు (Telugu)
    • ภาษาไทย (Thai)
    • Tiếng Việt (Vietnamese)
    • Čeština (Czech)
    • Polski (Polish)
    • Bahasa Indonesia (Indonesian)
    • Românește (Romanian)
    • Nederlands (Dutch)
    • Ελληνικά (Greek)
    • Latinum (Latin)
    • Svenska (Swedish)
    • Dansk (Danish)
    • Suomi (Finnish)
    • فارسی (Persian)
    • ייִדיש (Yiddish)
    • հայերեն (Armenian)
    • Norsk (Norwegian)
    • English (English)

    Citation

    Use the citation below to add these lyrics to your bibliography:

    Style:MLAChicagoAPA

    "Mo l'Olorun Lyrics." Lyrics.com. STANDS4 LLC, 2024. Web. 13 May 2024. <https://www.lyrics.com/sublyric/111657/Ola+Daniel/Mo+l%27Olorun>.

    We need you!

    Help build the largest human-edited lyrics collection on the web!

    Browse Lyrics.com

    Quiz

    Are you a music master?

    »
    "Pour some ___________".
    A Sugar on me
    B For the homies
    C Shook up ramen
    D Salt in it

    Free, no signup required:

    Add to Chrome

    Get instant explanation for any lyrics that hits you anywhere on the web!

    Free, no signup required:

    Add to Firefox

    Get instant explanation for any acronym or abbreviation that hits you anywhere on the web!