Okan Mi

PeterOfFaith

0 fans

PeterOfFaith


2:37

 Become A Better Singer In Only 30 Days, With Easy Video Lessons!

Ọkàn mí sí payá o
Òsì payá o
Lati keko
Ninu oro re
Okan mi si paya o
Osi paya o
Lati keko
Ninu oro re
Okan mi si paya ooo
Osi paya ooo
Lati keko
Ninu oro re
Okan mi si paya ya
Osi paya yayayaya
Osi paya o

Oro otito
Oro iye
Oro agbara
Oro itusile
Oro otito
Oro iye
Oro agbara
Oro imole
Oro otito
Oro iye
Oro agbara
Oro itusile lelele
I desire you Lord
My heart is open Lord

Okan mi si paya o
Osi paya o
Lati keko
Ninu oro re
Okan mi si paya o
Osi paya o
Lati keko
Ninu oro re
Okan mi si paya o
Osi paya o
Lati keko
Ninu oro re
Okan mi si paya o
Osi paya o
Lati keko
Ninu oro re

Oro otito
Oro iye
Oro agbara
Oro itusile
Oro otito
Oro iye
Oro agbara
Oro imole
Oro otito
Oro iye
Oro agbara
Oro itusile
Oro otito
Oro iye
Oro agbara
Oro itusile

Efesu
Ori kiini
Lati ese ikeedogun
Titi de ese iketalelogun
Ti oka bayi wipe
Notori eyi pelu
Nigba ti moti gburo
Igbagbo tiun be
Larin yin ninu Jesu oluwa
Ati ife yin si gbogbo
Awon eniyan mimo
Emi kosi simi
Lati ma dupe
Nitori yin
Ati lati ma daruko yin
Ninu aduro mi
Pe ki olorun
Jesu kristi oluwa wa
Baba ogo
Le fun yin ni
Emi nipa ti ogbon
Ati ifihan ninu imo re
Ki oju okan yin le mole
Ki eyin lemo
Ounti ireti ipin re je
Ati ounti oro ogo re
Ninu awon eniyan mimo
Ati agbara re ti o tobi julo
Si awa ti o gbagbo
Gege bi ise agbara re
Eyi ti o sise ninu kristi
Nigbati oti ji dide
‭‭
Femwondabeat

 Struggling with Okan Mi? Become a better singer in 30 days with these videos!

Written by: Olatunde Iyanuoluwa

Lyrics © DistroKid

Lyrics Licensed & Provided by LyricFind

Discuss the Okan Mi Lyrics with the community:

0 Comments

    Citation

    Use the citation below to add these lyrics to your bibliography:

    Style:MLAChicagoAPA

    "Okan Mi Lyrics." Lyrics.com. STANDS4 LLC, 2024. Web. 27 Apr. 2024. <https://www.lyrics.com/lyric-lf/11482788/PeterOfFaith/Okan+Mi>.

    Missing lyrics by PeterOfFaith?

    Know any other songs by PeterOfFaith? Don't keep it to yourself!

    Browse Lyrics.com

    Quiz

    Are you a music master?

    »
    Who sings the Nigerian song "Water no get enemy"?
    A Fela Kuti
    B Burna Boy
    C Olamide
    D Lucky Dube

    Free, no signup required:

    Add to Chrome

    Get instant explanation for any lyrics that hits you anywhere on the web!

    Free, no signup required:

    Add to Firefox

    Get instant explanation for any acronym or abbreviation that hits you anywhere on the web!

    PeterOfFaith tracks

    On Radio Right Now

    Loading...

    Powered by OnRad.io


    Think you know music? Test your MusicIQ here!