Okan Mi
PeterOfFaith
The easy, fast & fun way to learn how to sing: 30DaySinger.com
Ọkàn mí sí payá o Òsì payá o Lati keko Ninu oro re Okan mi si paya o Osi paya o Lati keko Ninu oro re Okan mi si paya ooo Osi paya ooo Lati keko Ninu oro re Okan mi si paya ya Osi paya yayayaya Osi paya o Oro otito Oro iye Oro agbara Oro itusile Oro otito Oro iye Oro agbara Oro imole Oro otito Oro iye Oro agbara Oro itusile lelele I desire you Lord My heart is open Lord Okan mi si paya o Osi paya o Lati keko Ninu oro re Okan mi si paya o Osi paya o Lati keko Ninu oro re Okan mi si paya o Osi paya o Lati keko Ninu oro re Okan mi si paya o Osi paya o Lati keko Ninu oro re Oro otito Oro iye Oro agbara Oro itusile Oro otito Oro iye Oro agbara Oro imole Oro otito Oro iye Oro agbara Oro itusile Oro otito Oro iye Oro agbara Oro itusile Efesu Ori kiini Lati ese ikeedogun Titi de ese iketalelogun Ti oka bayi wipe Notori eyi pelu Nigba ti moti gburo Igbagbo tiun be Larin yin ninu Jesu oluwa Ati ife yin si gbogbo Awon eniyan mimo Emi kosi simi Lati ma dupe Nitori yin Ati lati ma daruko yin Ninu aduro mi Pe ki olorun Jesu kristi oluwa wa Baba ogo Le fun yin ni Emi nipa ti ogbon Ati ifihan ninu imo re Ki oju okan yin le mole Ki eyin lemo Ounti ireti ipin re je Ati ounti oro ogo re Ninu awon eniyan mimo Ati agbara re ti o tobi julo Si awa ti o gbagbo Gege bi ise agbara re Eyi ti o sise ninu kristi Nigbati oti ji dide Femwondabeat
Struggling with Okan Mi? Become a better singer in 30 days with these videos!
Citation
Use the citation below to add these lyrics to your bibliography:
Style:MLAChicagoAPA
"Okan Mi Lyrics." Lyrics.com. STANDS4 LLC, 2024. Web. 11 May 2024. <https://www.lyrics.com/lyric-lf/11482788/PeterOfFaith/Okan+Mi>.
Discuss the Okan Mi Lyrics with the community:
Report Comment
We're doing our best to make sure our content is useful, accurate and safe.
If by any chance you spot an inappropriate comment while navigating through our website please use this form to let us know, and we'll take care of it shortly.
Attachment
You need to be logged in to favorite.
Log In